1
1 Ọba 22:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“OLúWA sì béèrè pé, ‘Báwo?’ “Ó sì wí pé, ‘Èmi yóò jáde lọ, èmi yóò sì di ẹ̀mí èké ní ẹnu gbogbo àwọn wòlíì rẹ̀.’ “OLúWA sì wí pé, ‘Ìwọ yóò tàn án, ìwọ yóò sì borí, jáde lọ, kí o sì ṣe bẹ́ẹ̀.’
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 1 Ọba 22:22
2
1 Ọba 22:23
“Bẹ́ẹ̀ ni OLúWA ti fi ẹ̀mí èké sí ẹnu gbogbo àwọn wòlíì rẹ wọ̀nyí. OLúWA sì ti sọ ibi sí ọ.”
Ṣàwárí 1 Ọba 22:23
3
1 Ọba 22:21
Ẹ̀mí kan sì jáde wá, ó sì dúró níwájú OLúWA, ó sì wí pé, ‘Èmi yóò tàn án.’
Ṣàwárí 1 Ọba 22:21
4
1 Ọba 22:20
OLúWA sì wí pé, ‘Ta ni yóò tan Ahabu láti kọlu Ramoti Gileadi? Kí ó sì tọ ikú rẹ̀ lọ níbẹ̀?’ “Ẹnìkan wí báyìí, ẹlòmíràn sì sọ òmíràn.
Ṣàwárí 1 Ọba 22:20
5
1 Ọba 22:7
Ṣùgbọ́n Jehoṣafati béèrè pé, “Ǹjẹ́ wòlíì OLúWA kan kò sí níhìn-ín, tí àwa ìbá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀?”
Ṣàwárí 1 Ọba 22:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò