1 Ọba 22:21

1 Ọba 22:21 YCB

Ẹ̀mí kan sì jáde wá, ó sì dúró níwájú OLúWA, ó sì wí pé, ‘Èmi yóò tàn án.’