1
Ìṣe àwọn Aposteli 10:34-35
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Peteru sì ya ẹnu rẹ, ó sì wí pé, “Nítòótọ́ mo wòye pé, Ọlọ́run kì í ṣe ojúsàájú ènìyàn. Ṣùgbọ́n ni gbogbo orílẹ̀-èdè, ẹni tí ó bá bẹ̀rù rẹ̀, ti ó sì ń ṣiṣẹ́ òdodo, ẹni ìtẹ́wọ́gbà ni lọ́dọ̀ rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 10:34-35
2
Ìṣe àwọn Aposteli 10:43
Òun ni gbogbo àwọn wòlíì jẹ́rìí sì pé, ẹnikẹ́ni ti ó bá gbà á gbọ́ yóò rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà nípa orúkọ rẹ̀.”
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 10:43
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò