Ìṣe àwọn Aposteli 10:43

Ìṣe àwọn Aposteli 10:43 YCB

Òun ni gbogbo àwọn wòlíì jẹ́rìí sì pé, ẹnikẹ́ni ti ó bá gbà á gbọ́ yóò rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà nípa orúkọ rẹ̀.”