1
Ìṣe àwọn Aposteli 3:19
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí náà ẹ ronúpìwàdà, kí ẹ sì yípadà sí Ọlọ́run, kí a lè pa ẹ̀ṣẹ̀ yín rẹ́, kí àkókò ìtura bá a lè ti ọ̀dọ̀ Olúwa wá
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 3:19
2
Ìṣe àwọn Aposteli 3:6
Peteru wí pé, “Wúrà àti fàdákà èmi kò ní, ṣùgbọ́n ohun tí mo ní èyí náà ni mo fi fún ọ: Ní orúkọ Jesu Kristi ti Nasareti, dìde kí o sì máa rìn.”
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 3:6
3
Ìṣe àwọn Aposteli 3:7-8
Ó sì fà á lọ́wọ́ ọ̀tún, ó sì gbé dìde; lójúkan náà ẹsẹ̀ rẹ̀ àti egungun kókósẹ̀ rẹ̀ sì mókun. Ó sì ń fò sókè, ó dúró, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí rìn, ó sì bá wọn wọ inú tẹmpili lọ, ó ń rìn, ó sì ń fò, ó sì yín Ọlọ́run.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 3:7-8
4
Ìṣe àwọn Aposteli 3:16
Nípa ìgbàgbọ́ nínú orúkọ Jesu, òun ni ó mú ọkùnrin yìí láradá, ẹni tí ẹ̀yin rí, tí ẹ sì mọ̀. Orúkọ Jesu àti ìgbàgbọ́ tí ó wá nípa rẹ̀ ni ó fún un ní ìlera pípé ṣáṣá yìí ni ojú gbogbo yín.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 3:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò