1
Ìṣe àwọn Aposteli 4:12
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kò sì sí ìgbàlà lọ́dọ̀ ẹlòmíràn; nítorí kò sí orúkọ mìíràn lábẹ́ ọ̀run ti a fi fún ni nínú ènìyàn, nípa èyí tí a lè fi gbà wá là.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 4:12
2
Ìṣe àwọn Aposteli 4:31
Nígbà tí wọ́n gbàdúrà tan, ibi tí wọ́n gbé péjọpọ̀ sí mì tìtì; gbogbo wọn sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, wọ́n sì ń fi ìgboyà sọ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 4:31
3
Ìṣe àwọn Aposteli 4:29
Ǹjẹ́ nísinsin yìí, Olúwa, kíyèsi ìhàlẹ̀ wọn; kí ó sì fi fún àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ láti máa fi ìgboyà ńlá sọ ọ̀rọ̀ rẹ.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 4:29
4
Ìṣe àwọn Aposteli 4:11
Èyí ni “ ‘òkúta tí a ti ọwọ́ ẹ̀yin ọ̀mọ̀lé kọ̀sílẹ̀, tí ó sì di pàtàkì igun ilé.’
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 4:11
5
Ìṣe àwọn Aposteli 4:13
Nígbà tí wọ́n sì kíyèsi ìgboyà Peteru àti Johanu, tí wọ́n mọ̀ pé, aláìkẹ́kọ̀ọ́ àti òpè ènìyàn ni wọn, ẹnu yà wọ́n, wọ́n sì wòye pé, wọ́n ti ń bá Jesu gbé.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 4:13
6
Ìṣe àwọn Aposteli 4:32
Ìjọ àwọn tí ó gbàgbọ́ sì wà ní ọkàn kan àti inú kan; kò sì ṣí ẹnìkan tí ó wí pé ohun kan nínú ohun ìní rẹ̀ jẹ́ ti ara rẹ̀; ṣùgbọ́n gbogbo wọn ní ohun gbogbo ní ìṣọ̀kan.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 4:32
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò