1
Esekiẹli 15:8
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Èmi yóò sọ ilé náà di ahoro nítorí ìwà àìṣòótọ́ wọn, ni OLúWA Olódùmarè wí.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esekiẹli 15:8
2
Esekiẹli 15:7
Èmi yóò dojúkọ wọ́n. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọn ti jáde kúrò nínú iná kan, síbẹ̀ iná mìíràn yóò pàpà jó wọn. Nígbà tí mo bá sì dojúkọ wọ́n, ẹ̀yin yóò sì mọ̀ pé, Èmi ni OLúWA.
Ṣàwárí Esekiẹli 15:7