1
Habakuku 1:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Ẹ wo inú àwọn kèfèrí, ki ẹ sí wòye, Kí háà kí ó sì ṣe yin gidigidi. Nítorí èmi ó ṣe ohun kan ní ọjọ́ yín tí ẹ̀yin kò jẹ́ gbàgbọ́, bí a tilẹ̀ sọ fún yin.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Habakuku 1:5
2
Habakuku 1:2
OLúWA, èmi yóò ti ké pẹ́ tó fún ìrànlọ́wọ́, Ṣùgbọ́n ti ìwọ kò ni fetí sí mi? Tàbí kígbe sí ọ ní ti, “Ìwà ipá!” ṣùgbọ́n tí ìwọ kò sì gbàlà?
Ṣàwárí Habakuku 1:2
3
Habakuku 1:3
Èéṣe tí ìwọ fi mú mi rí àìṣedéédéé Èéṣe tí ìwọ sì fi ààyè gba ìwà ìkà? Ìparun àti ìwà ipá wà ní iwájú mi; ìjà ń bẹ, ìkọlù sì wà pẹ̀lú.
Ṣàwárí Habakuku 1:3
4
Habakuku 1:4
Nítorí náà, òfin di ohun àìkàsí, ìdájọ́ òdodo kò sì borí. Àwọn ẹni búburú yí àwọn olódodo ká, Nítorí náà ni ìdájọ́ òdodo ṣe yí padà.
Ṣàwárí Habakuku 1:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò