1
Isaiah 23:18
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Síbẹ̀síbẹ̀ èrè rẹ̀ àti owó iṣẹ́ rẹ̀ ni a ó yà sọ́tọ̀ fún OLúWA; a kò ní kó wọn pamọ́ tàbí kí a há wọn mọ́wọ́. Ère rẹ̀ ni a ó fi fún àwọn tí ó ń gbé níwájú OLúWA, fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ àti aṣọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isaiah 23:18
2
Isaiah 23:9
OLúWA àwọn ọmọ-ogun ti ṣètò rẹ̀, láti tẹrí ìgbéraga àti ògo rẹ ba àti láti rẹ gbogbo àwọn ọlọ́lá ilé ayé sílẹ̀.
Ṣàwárí Isaiah 23:9
3
Isaiah 23:1
Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Tire: Hu, ìwọ ọkọ̀ ojú omi Tarṣiṣi! Nítorí a ti pa Tire run láìsí ilé tàbí èbúté. Láti ilẹ̀ Saipurọsi ni ọ̀rọ̀ ti wá sọ́dọ̀ wọn.
Ṣàwárí Isaiah 23:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò