Isaiah 23:18

Isaiah 23:18 YCB

Síbẹ̀síbẹ̀ èrè rẹ̀ àti owó iṣẹ́ rẹ̀ ni a ó yà sọ́tọ̀ fún OLúWA; a kò ní kó wọn pamọ́ tàbí kí a há wọn mọ́wọ́. Ère rẹ̀ ni a ó fi fún àwọn tí ó ń gbé níwájú OLúWA, fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ àti aṣọ.