1
Isaiah 37:16
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Israẹli, tí ó gúnwà láàrín àwọn kérúbù, ìwọ nìkan ni Ọlọ́run lórí i gbogbo ìjọba orílẹ̀ ayé. Ìwọ ti dá ọ̀run àti ayé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isaiah 37:16
2
Isaiah 37:20
Nísinsin yìí, ìwọ OLúWA, Ọlọ́run wa, gbà wá lọ́wọ́ rẹ̀, tí ó fi jẹ́ pé gbogbo ìjọba ilẹ̀ ayé yóò fi mọ̀ pé Ìwọ, Ìwọ nìkan, OLúWA ni Ọlọ́run.”
Ṣàwárí Isaiah 37:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò