1
Jeremiah 1:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kí ó tó di pé mo dá ọ láti inú ni mo ti mọ̀ ọ́n, kí ó sì tó di pé a bí ọ ni mo ti yà ọ́ sọ́tọ̀. Mo yàn ọ́ gẹ́gẹ́ bí wòlíì fún àwọn orílẹ̀-èdè.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jeremiah 1:5
2
Jeremiah 1:8
OLúWA sì wí pé má ṣe bẹ̀rù wọn, nítorí tí èmi wà pẹ̀lú rẹ èmi ó sì gbà ọ́.
Ṣàwárí Jeremiah 1:8
3
Jeremiah 1:19
Wọn yóò dojú ìjà kọ ọ́, wọn kì yóò borí rẹ, nítorí wí pé èmi wà pẹ̀lú rẹ, èmi yóò sì gbà ọ́,” ni OLúWA wí.
Ṣàwárí Jeremiah 1:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò