1
Jeremiah 2:13
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Àwọn ènìyàn mi ti dẹ́ṣẹ̀ méjì Wọ́n ti kọ̀ mí sílẹ̀, Èmi orísun omi ìyè, wọ́n sì ti ṣe àmù, àmù fífọ́ tí kò lè gba omi dúró.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jeremiah 2:13
2
Jeremiah 2:19
Iṣẹ́ búburú yín yóò fìyà jẹ yín ìpadàsẹ́yìn rẹ yóò sì bá ọ wí mọ̀ kí o sì rí i wí pé ibi àti ohun búburú yóò sì jẹ́ tìrẹ nígbà tí o ti kọ OLúWA Ọlọ́run sílẹ̀, ẹ kò sì ní ìbẹ̀rù fún mi,” ni Olúwa, OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí.
Ṣàwárí Jeremiah 2:19
3
Jeremiah 2:11
Orílẹ̀-èdè kan ha á pa Ọlọ́run rẹ̀ dà? (Síbẹ̀, wọ́n kì í ṣe iṣẹ́ Ọlọ́run) àwọn ènìyàn mi ti pààrọ̀ ògo wọn fún àwọn ère tí kò níyì.
Ṣàwárí Jeremiah 2:11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò