1
Jeremiah 13:23
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ǹjẹ́ Etiopia le yí àwọ̀ rẹ̀ padà? Tàbí ẹkùn lè yí àwọ̀ rẹ̀ padà? Bí èyí kò ti lè rí bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀yin tí ìwà búburú bá ti mọ́ lára kò lè ṣe rere.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jeremiah 13:23
2
Jeremiah 13:16
Ẹ fi ògo fún OLúWA Ọlọ́run yín, kí ó tó mú òkùnkùn wá, àti kí ó tó mú ẹsẹ̀ yín tàsé lórí òkè tí ó ṣókùnkùn, Nígbà tí ẹ̀yin sì ń retí ìmọ́lẹ̀, òun yóò sọ ọ́ di òjìji yóò sì ṣe bi òkùnkùn biribiri.
Ṣàwárí Jeremiah 13:16
3
Jeremiah 13:10
Àwọn ènìyàn búburú tí ó kùnà láti gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, tí wọ́n ń lo agídí ọkàn wọn, tí ó sì ń rìn tọ àwọn òrìṣà láti sìn wọ́n, àti láti foríbalẹ̀ fún wọn, yóò sì dàbí àmùrè yìí tí kò wúlò fún ohunkóhun.
Ṣàwárí Jeremiah 13:10
4
Jeremiah 13:15
Gbọ́ kí o sì fetísílẹ̀, ẹ má ṣe gbéraga, nítorí OLúWA ti sọ̀rọ̀.
Ṣàwárí Jeremiah 13:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò