1
Jeremiah 14:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ǹjẹ́ èyíkéyìí àwọn òrìṣà yẹ̀yẹ́ tí àwọn orílẹ̀-èdè le ṣe kí òjò rọ̀? Ǹjẹ́ àwọsánmọ̀ fúnrarẹ̀ rọ òjò bí? Rárá, ìwọ ni, OLúWA Ọlọ́run wa. Torí náà, ìrètí wa wà lọ́dọ̀ rẹ, nítorí pé ìwọ lo ń ṣe gbogbo nǹkan wọ̀nyí.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jeremiah 14:22
2
Jeremiah 14:7
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀ṣẹ̀ wa jẹ́rìí lòdì sí wa, wá nǹkan kan ṣe sí i OLúWA, nítorí orúkọ rẹ. Nítorí ìpadàsẹ́yìn wa ti pọ̀jù, a ti ṣẹ̀ sí ọ.
Ṣàwárí Jeremiah 14:7
3
Jeremiah 14:20-21
OLúWA, a jẹ́wọ́ ìwà ibi wa àti àìṣedéédéé àwọn baba wa; lóòótọ́ ni a ti ṣẹ̀ sí ọ. Nítorí orúkọ rẹ má ṣe kórìíra wa; má ṣe sọ ìtẹ́ ògo rẹ di àìlọ́wọ̀. Rántí májẹ̀mú tí o bá wa dá kí o má ṣe dà á.
Ṣàwárí Jeremiah 14:20-21
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò