1
Jobu 17:9
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Olódodo pẹ̀lú yóò di ọ̀nà rẹ̀ mú, àti ọlọ́wọ́ mímọ́ yóò máa lera síwájú.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jobu 17:9
2
Jobu 17:3
“Fi fún mi Olúwa, ìlérí tí ìwọ fẹ́; ta ni yóò le ṣe ààbò fún mi?
Ṣàwárí Jobu 17:3
3
Jobu 17:1
“Ẹ̀mí mi bàjẹ́, ọjọ́ mi ni a ti gé kúrú, isà òkú dúró dè mí.
Ṣàwárí Jobu 17:1
4
Jobu 17:11-12
Ọjọ́ tí èmi ti kọjá, ìrò mi ti fà yá, àní ìrò ọkàn mi. Àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń ṣọ́ òru di ọ̀sán; wọ́n ní, ìmọ́lẹ̀ súnmọ́ ibi tí òkùnkùn dé.
Ṣàwárí Jobu 17:11-12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò