1
Jobu 18:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Nítòótọ́ ìmọ́lẹ̀ ènìyàn búburú ni a ó pa kúrò, Ọ̀wọ́-iná rẹ̀ kì yóò sì tan ìmọ́lẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jobu 18:5
2
Jobu 18:6
Ìmọ́lẹ̀ yóò di òkùnkùn nínú àgọ́ rẹ̀, fìtílà ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ni a ó sì pa pẹ̀lú.
Ṣàwárí Jobu 18:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò