1
Jobu 36:11
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Bí wọ́n bá gbàgbọ́ tí wọ́n sì sìn ín, wọn ó lo ọjọ́ wọn ní ìrọ̀rùn, àti ọdún wọn nínú afẹ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jobu 36:11
2
Jobu 36:5
“Kíyèsi i, Ọlọ́run ni alágbára, òun kò i sì gàn ènìyàn; ó ní agbára ní ipá àti òye.
Ṣàwárí Jobu 36:5
3
Jobu 36:15
Òun gba òtòṣì nínú ìpọ́njú wọn, a sì sọ̀rọ̀ sí wọn ní etí nínú ìnira wọn.
Ṣàwárí Jobu 36:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò