1
Jobu 37:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ọlọ́run fi ohùn rẹ̀ sán àrá ní ọ̀nà ìyanu; ohùn ńláńlá ni í ṣe tí àwa kò le mọ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jobu 37:5
2
Jobu 37:23
Nípa ti Olódùmarè àwa kò le wádìí rẹ̀, ó rékọjá ní ipá; nínú ìdájọ́ àti títí bi òun kì í ba ẹ̀tọ́ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ òtítọ́ jẹ́.
Ṣàwárí Jobu 37:23
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò