1
Lefitiku 20:13
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
“ ‘Bí ọkùnrin kan bá bá ọkùnrin mìíràn lòpọ̀ bí wọ́n ti í bá obìnrin lòpọ̀: àwọn méjèèjì ti ṣe ohun ìríra, pípa ni kí ẹ pa wọ́n, ẹ̀jẹ̀ wọn yóò wà lórí wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Lefitiku 20:13
2
Lefitiku 20:7
“ ‘Torí náà ẹ ya ara yín sí mímọ́ kí ẹ sì jẹ́ mímọ́, torí pé, Èmi ni OLúWA Ọlọ́run yín.
Ṣàwárí Lefitiku 20:7
3
Lefitiku 20:26
Ẹ gbọdọ̀ jẹ́ mímọ́ fún mi torí pé, Èmi OLúWA fẹ́ mímọ́. Mó sì ti yà yín kúrò nínú àwọn orílẹ̀-èdè yòókù kí ẹ le jẹ́ tèmi.
Ṣàwárí Lefitiku 20:26
4
Lefitiku 20:8
Ẹ máa kíyèsi àṣẹ mi, kí ẹ sì máa pa wọ́n mọ́. Èmi ni OLúWA tí ó sọ yín di mímọ́.
Ṣàwárí Lefitiku 20:8