1
Numeri 12:8
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Mo sì ń bá a sọ̀rọ̀ ní ojúkojú, ọ̀rọ̀ yékéyéké tí kì í ṣe òwe, ó rí àwòrán OLúWA Kí ló wá dé tí ẹ̀yin kò ṣe bẹ̀rù láti sọ̀rọ̀-òdì sí Mose ìránṣẹ́ mi?”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Numeri 12:8
2
Numeri 12:3
(Mose sì jẹ́ ọlọ́kàn tútù ju gbogbo ènìyàn tó wà lórí ilẹ̀ ayé lọ).
Ṣàwárí Numeri 12:3
3
Numeri 12:6
Ó wí pé, “Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi: “Bí wòlíì OLúWA bá wà láàrín yín Èmi OLúWA a máa fi ara à mi hàn án ní ojúran, Èmi a máa bá a sọ̀rọ̀ nínú àlá.
Ṣàwárí Numeri 12:6
4
Numeri 12:7
Ṣùgbọ́n èyí kò rí bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú Mose ìránṣẹ́ mi: ó jẹ́ olóòtítọ́ nínú gbogbo ilé mi.
Ṣàwárí Numeri 12:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò