1
Numeri 22:28
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nígbà náà OLúWA ṣí ẹnu kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ó sì sọ fún Balaamu pé, “Kí ni mo ṣe fún ọ tí o fi nà mí lẹ́ẹ̀mẹ́ta?”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Numeri 22:28
2
Numeri 22:31
Nígbà náà OLúWA ṣí ojú Balaamu, ó sì rí angẹli OLúWA tí ó dúró ní ojú ọ̀nà pẹ̀lú idà rẹ̀ tí ó fàyọ. Ó sì tẹ orí rẹ̀ ba.
Ṣàwárí Numeri 22:31
3
Numeri 22:32
Nígbà náà angẹli OLúWA béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Kí ni ó dé tí o fi na kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ nígbà mẹ́ta yìí? Mo wá síbí láti kọ ojú ìjà sí ọ nítorí ọ̀nà rẹ kò tọ́ níwájú mi.
Ṣàwárí Numeri 22:32
4
Numeri 22:30
Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sọ fún Balaamu pé, “Ṣé mi kì í ṣe kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ ni, tí o máa ń gùn ní gbogbo ìgbà, láti ìgbà pípẹ́ wá? Ǹjẹ́ mo hu irú ìwà báyìí sí ọ rí?” “Rárá,” Ó dáhùn.
Ṣàwárí Numeri 22:30
5
Numeri 22:29
Balaamu sọ fún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ pé, “Nítorí ìwọ fi mí ṣẹ̀sín! Bí mo bá ní idà ní ọwọ́ ni èmi ìbá pa ọ́ nísinsin yìí.”
Ṣàwárí Numeri 22:29
6
Numeri 22:27
Nígbà tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rí angẹli OLúWA, ó sì jókòó ní abẹ́ Balaamu, inú sì bí i tó sì nà án pẹ̀lú ọ̀pá rẹ̀.
Ṣàwárí Numeri 22:27
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò