1
Òwe 10:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ìbùkún OLúWA ń mú ọrọ̀ wá, kì í sì í fi ìdààmú sí i.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Òwe 10:22
2
Òwe 10:19
Nínú ọ̀rọ̀ púpọ̀ a kò le fẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ kù ṣùgbọ́n ẹni tí ó pa ẹnu rẹ̀ mọ́ jẹ́ ọlọ́gbọ́n.
Ṣàwárí Òwe 10:19
3
Òwe 10:12
Ìríra a máa dá ìjà sílẹ̀, ṣùgbọ́n ìfẹ́ a máa bo gbogbo àṣìṣe mọ́lẹ̀.
Ṣàwárí Òwe 10:12
4
Òwe 10:4
Ọwọ́ tí ó lẹ máa ń sọ ènìyàn di tálákà, ṣùgbọ́n ọwọ́ tí ó múra ṣíṣẹ́ a máa sọ ni di ọlọ́rọ̀.
Ṣàwárí Òwe 10:4
5
Òwe 10:17
Ẹni tí ó gbọ́ ìbáwí fi ọ̀nà sí ìyè hàn ṣùgbọ́n ẹni tí ó kọ ìbáwí mú àwọn mìíràn ṣìnà.
Ṣàwárí Òwe 10:17
6
Òwe 10:9
Ẹni tí ó ń rìn déédé, ń rìn láìléwu ṣùgbọ́n àṣírí ẹni tí ń rin ọ̀nà pálapàla yóò tú.
Ṣàwárí Òwe 10:9
7
Òwe 10:27
Ìbẹ̀rù OLúWA ń mú ọjọ́ ayé gígùn wá, ṣùgbọ́n a gé ọjọ́ ayé ènìyàn búburú kúrú.
Ṣàwárí Òwe 10:27
8
Òwe 10:3
OLúWA kì í jẹ́ kí ebi máa pa olódodo ṣùgbọ́n ó ba ète àwọn ènìyàn búburú jẹ́.
Ṣàwárí Òwe 10:3
9
Òwe 10:25
Nígbà tí ìjì bá ti jà kọjá, ènìyàn búburú a kọjá lọ, ṣùgbọ́n Olódodo yóò dúró ṣinṣin láéláé.
Ṣàwárí Òwe 10:25
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò