1
Saamu 10:17-18
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ìwọ́ gbọ́, OLúWA, ìfẹ́ àwọn tí a ni lára; Ìwọ gbà wọ́n níyànjú, ó sì gbọ́ igbe wọn, Láti ṣe ìdájọ́ àwọn aláìní baba àti àwọn ti a ni lára, kí ọkùnrin, tí ó wà ní ayé, kí ó má ṣe dẹ́rùbà ni mọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 10:17-18
2
Saamu 10:14
Ṣùgbọ́n ìwọ, Ọlọ́run, ni ó rí wàhálà àti ìrora; Ìwọ rò láti fi sí ọwọ́ rẹ. Tálákà fi ara rẹ̀ jì fún ọ; Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ àwọn aláìní baba.
Ṣàwárí Saamu 10:14
3
Saamu 10:1
Èéha ti ṣe, OLúWA, tí ìwọ fi dúró ní òkè réré? Èéha ti ṣe, tí ìwọ fi ara rẹ pamọ́ ní ìgbà ìpọ́njú?
Ṣàwárí Saamu 10:1
4
Saamu 10:12
Dìde, OLúWA! Gbé ọwọ́ rẹ sókè, Ọlọ́run. Má ṣe gbàgbé àwọn olùpọ́njú.
Ṣàwárí Saamu 10:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò