1
Saamu 11:7
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí, olódodo ní OLúWA, o fẹ́ràn òdodo; ẹni ìdúró ṣinṣin yóò sì rí i.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 11:7
2
Saamu 11:4
OLúWA ń bẹ nínú tẹmpili mímọ́ rẹ̀; OLúWA ń bẹ lórí ìtẹ́ rẹ̀ ní ọ̀run. Ó ń wo àwọn ọmọ ènìyàn; ojú rẹ̀ ń yẹ̀ wọ́n wò.
Ṣàwárí Saamu 11:4
3
Saamu 11:5
OLúWA ń yẹ olódodo wò, ṣùgbọ́n ènìyàn búburú àti àwọn tí o fẹ́ ìwà ipá ni ọkàn rẹ̀ kórìíra.
Ṣàwárí Saamu 11:5
4
Saamu 11:3
Nígbà tí ìpìlẹ̀ bá bàjẹ́ kí ni olódodo yóò ṣe?”
Ṣàwárí Saamu 11:3
5
Saamu 11:1
Ìgbẹ́kẹ̀lé mi wà nínú OLúWA. Báwo ní ẹ̀yin ó ṣe sọ fún ọkàn mi pé: “Fò gẹ́gẹ́ bi ẹyẹ lọ si orí òkè rẹ.
Ṣàwárí Saamu 11:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò