1
Saamu 100:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí tí OLúWA pọ̀ ní oore ìfẹ́ rẹ̀ sì wà títí láé; àti òtítọ́ rẹ̀ láti ìran de ìran.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 100:5
2
Saamu 100:4
Ẹ lọ sí ẹnu-ọ̀nà rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́ àti sí àgbàlá rẹ̀ pẹ̀lú ìyìn; ẹ fi ọpẹ́ àti ìyìn fún orúkọ rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 100:4
3
Saamu 100:2
Ẹ fi ayọ̀ sin OLúWA: Ẹ wá síwájú rẹ̀ pẹ̀lú orin dídùn
Ṣàwárí Saamu 100:2
4
Saamu 100:3
OLúWA Ọlọ́run ni ó dá wa, kí ẹ̀yin kí ó mọ̀ pé tirẹ̀ ni àwa; Àwa ní ènìyàn rẹ̀ àti àgùntàn pápá rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 100:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò