1
Saamu 101:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi kì yóò gbé ohun búburú sí iwájú mi: iṣẹ́ àwọn tí ó yapa ni èmi kórìíra. Wọn kì yóò rọ̀ mọ́ mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 101:3
2
Saamu 101:2
Èmi yóò máa rin ìrìn mi pẹ̀lú ọgbọ́n láìlẹ́ṣẹ̀, ìgbà wo ni ìwọ yóò wá sí ọ̀dọ̀ mi? Èmi yóò máa rìn ní ilé mi pẹ̀lú àyà pípé.
Ṣàwárí Saamu 101:2
3
Saamu 101:6
Ojú mi yóò wà lára àwọn olóòtítọ́ lórí ilẹ̀, kí wọn kí ó lè máa bá mi gbé; ẹni tí ó bá n rin ọ̀nà pípé òun ni yóò máa sìn mí.
Ṣàwárí Saamu 101:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò