1
Saamu 102:2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Má ṣe pa ojú rẹ mọ́ kúrò lọ́dọ̀ mi ní ọjọ́ tí èmi wà nínú ìpọ́njú. Dẹ etí rẹ sí mi; nígbà tí mo bá pè, dá mi lóhùn kíákíá.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 102:2
2
Saamu 102:1
Gbọ́ àdúrà mi, OLúWA: Jẹ́ kí igbe ẹ̀bẹ̀ mi kí ó wá sí ọ̀dọ̀ rẹ
Ṣàwárí Saamu 102:1
3
Saamu 102:12
Ṣùgbọ́n ìwọ, OLúWA, ni yóò dúró láéláé; ìrántí rẹ láti ìran dé ìran.
Ṣàwárí Saamu 102:12
4
Saamu 102:17
Yóò dáhùn àdúrà àwọn aláìní; kì yóò sì gan ẹ̀bẹ̀ wọn.
Ṣàwárí Saamu 102:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò