1
Saamu 108:13
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nípasẹ̀ Ọlọ́run ni àwa ó ṣe akin nítorí òun ó tẹ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 108:13
2
Saamu 108:4
Nítorí tí o tóbi ní àánú rẹ ju àwọn ọ̀run lọ àti òdodo rẹ dé àwọsánmọ̀
Ṣàwárí Saamu 108:4
3
Saamu 108:1
Ọlọ́run, ọkàn mi dúró ṣinṣin èmi ó máa kọrin, èmi ó máa fi ọkàn mi kọrin
Ṣàwárí Saamu 108:1
4
Saamu 108:12
Fún wa ní ìrànlọ́wọ́ nínú ìpọ́njú, nítorí ìrànlọ́wọ́ ènìyàn asán ni.
Ṣàwárí Saamu 108:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò