1
Saamu 109:30
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Pẹ̀lú ẹnu mi èmi yóò máa yin OLúWA gidigidi ní àárín ọ̀pọ̀ ènìyàn èmi yóò máa yìn ín
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 109:30
2
Saamu 109:26
Ràn mí lọ́wọ́, OLúWA Ọlọ́run mi; gbà mí gẹ́gẹ́ bí ìṣeun ìfẹ́ rẹ.
Ṣàwárí Saamu 109:26
3
Saamu 109:31
Nítorí ó dúró ní apá ọ̀tún aláìní láti gbà á lọ́wọ́ àwọn tí ń dá ọkàn rẹ̀ lẹ́bi.
Ṣàwárí Saamu 109:31
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò