1
Saamu 115:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kì í ṣe fún wa, OLúWA kì í ṣe fún wa, ṣùgbọ́n fún orúkọ rẹ ni a fi ògo fún, fún àánú àti òtítọ́ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 115:1
2
Saamu 115:14
OLúWA yóò mú ọ pọ̀ sí i síwájú àti síwájú, ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 115:14
3
Saamu 115:11
Ẹ̀ yin tí ó bẹ̀rù OLúWA, gbẹ́kẹ̀lé OLúWA: òun ní ìrànwọ́ àti ààbò wọn.
Ṣàwárí Saamu 115:11
4
Saamu 115:15
Ẹ fi ìbùkún fún OLúWA ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayé.
Ṣàwárí Saamu 115:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò