1
Saamu 116:1-2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi fẹ́ràn OLúWA, nítorí ó gbọ́ ohùn mi; ó gbọ́ ẹkún mi fún àánú. Nítorí ó yí etí rẹ̀ padà sí mi, èmi yóò máa pè é ni wọ́n ìgbà tí mo wà láààyè.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 116:1-2
2
Saamu 116:5
OLúWA ní oore-ọ̀fẹ́, ó sì ní òdodo; Ọlọ́run wa kún fún àánú.
Ṣàwárí Saamu 116:5
3
Saamu 116:15
Iyebíye ní ojú OLúWA àti ikú àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 116:15
4
Saamu 116:8-9
Nítorí ìwọ, OLúWA, ti gba ọkàn mi kúrò lọ́wọ́ ikú, ojú mi kúrò lọ́wọ́ omijé, àti ẹsẹ̀ mi kúrò lọ́wọ́ ìṣubú, Nítorí èmi yóò máa rìn níwájú OLúWA ní ilẹ̀ alààyè.
Ṣàwárí Saamu 116:8-9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò