1
Saamu 117:2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa, àti òtítọ́ OLúWA dúró láéláé. Ẹ yin OLúWA!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 117:2
2
Saamu 117:1
Ẹ yin OLúWA, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn.
Ṣàwárí Saamu 117:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò