1
Saamu 135:6
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA ṣe ohunkóhun tí ó wù ú, ní ọ̀run àti ní ayé, ní Òkun àti ní ọ̀gbun gbogbo.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 135:6
2
Saamu 135:3
Ẹ yin OLúWA: nítorí tí OLúWA ṣeun; ẹ kọrin ìyìn sí orúkọ rẹ̀; nítorí tí ó dùn.
Ṣàwárí Saamu 135:3
3
Saamu 135:13
OLúWA orúkọ rẹ dúró láéláé; ìrántí rẹ OLúWA, láti ìrandíran.
Ṣàwárí Saamu 135:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò