1
Saamu 136:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA nítorí tí ó ṣeun; nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 136:1
2
Saamu 136:26
Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run ọ̀run; nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.
Ṣàwárí Saamu 136:26
3
Saamu 136:2
Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run àwọn ọlọ́run: nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.
Ṣàwárí Saamu 136:2
4
Saamu 136:3
Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa àwọn olúwa, nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.
Ṣàwárí Saamu 136:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò