1
Saamu 63:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ọlọ́run, ìwọ ni Ọlọ́run mi, nígbà gbogbo ni mo ń ṣàfẹ́rí rẹ, òǹgbẹ rẹ ń gbẹ ọkàn mi, ara mi fà sí ọ, ní ilẹ̀ gbígbẹ àti ilẹ̀ tí ń ṣàárẹ̀ níbi tí kò sí omi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 63:1
2
Saamu 63:3
Nítorí ìfẹ́ rẹ dára ju ayé lọ, ètè mi yóò fògo fún ọ.
Ṣàwárí Saamu 63:3
3
Saamu 63:4
Èmi ó yìn ọ́ níwọ̀n ìgbà tí mo wà láààyè, èmi ó gbé ọwọ́ sókè, èmi ó sì pe orúkọ rẹ.
Ṣàwárí Saamu 63:4
4
Saamu 63:2
Èmi ti rí ọ ní ibi mímọ́, mo rí agbára àti ògo rẹ.
Ṣàwárí Saamu 63:2
5
Saamu 63:7-8
Nítorí ìwọ ni ìrànlọ́wọ́ mi, mo kọrin níbi òjìji ìyẹ́ apá rẹ. Ọkàn mí fà sí ọ: ọwọ́ ọ̀tún rẹ gbé mi ró.
Ṣàwárí Saamu 63:7-8
6
Saamu 63:6
Nígbà tí mo rántí rẹ lórí ibùsùn mi; èmi ń ronú rẹ títí ìṣọ́ òru.
Ṣàwárí Saamu 63:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò