1
Saamu 65:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ìbùkún ni fún àwọn tí o yàn tí o mú wa láti máa gbé àgọ́ rẹ! A tẹ́ wá lọ́rùn pẹ̀lú ohun rere inú ilé rẹ, ti tẹmpili mímọ́ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 65:4
2
Saamu 65:11
Ìwọ fi oore rẹ dé ọdún ní adé, ọ̀rá ń kán ní ipa ọ̀nà rẹ
Ṣàwárí Saamu 65:11
3
Saamu 65:5
Ìwọ dá wa lóhùn pẹ̀lú ohun ìyanu ti òdodo, Ọlọ́run olùgbàlà wa, ẹni tí ṣe ìgbẹ́kẹ̀lé gbogbo òpin ayé àti àwọn tí ó jìnnà nínú Òkun
Ṣàwárí Saamu 65:5
4
Saamu 65:3
Ọ̀ràn àìṣedéédéé borí mi bí ó ṣe ti ìrékọjá wa ni! Ìwọ ni yóò wẹ̀ wọ́n nù kúrò.
Ṣàwárí Saamu 65:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò