1
Saamu 66:18
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Bí èmi bá gba ẹ̀ṣẹ̀ ní àyà mi, Olúwa kì yóò gbọ́ ohùn mi
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 66:18
2
Saamu 66:20
Ìyìn ni fún Ọlọ́run ẹni tí kò kọ àdúrà mi tàbí mú ìfẹ́ rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ mi!
Ṣàwárí Saamu 66:20
3
Saamu 66:3
Ẹ wí fún Ọlọ́run “pé, ìwọ ti ní ẹ̀rù tó nínú iṣẹ́ rẹ! Nípa ọ̀pọ̀ agbára rẹ ni àwọn ọ̀tá rẹ yóò fi sìn ọ́.
Ṣàwárí Saamu 66:3
4
Saamu 66:1-2
Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọ́run, ẹ̀yin ilẹ̀ gbogbo! Ẹ kọrin ọlá orúkọ rẹ̀; Ẹ kọrin ìyìnsí i
Ṣàwárí Saamu 66:1-2
5
Saamu 66:10
Nítorí ìwọ, Ọlọ́run, dán wa wò; ìwọ dán wa bí a tí ń dán fàdákà wò.
Ṣàwárí Saamu 66:10
6
Saamu 66:16
Ẹ wá gbọ́ gbogbo ẹ̀yin tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run; ẹ jẹ́ kí n sọ ohun tí ó ṣe fún mi.
Ṣàwárí Saamu 66:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò