1
Saamu 67:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kí Ọlọ́run kí ó ṣàánú fún wa kí ó sì bùkún fún wa, kí ó sì jẹ́ kí ojú rẹ̀ tàn yí wa ká
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 67:1
2
Saamu 67:7
Ọlọ́run yóò bùkún fún wa, àti gbogbo òpin ilẹ̀ ayé yóò sì máa bẹ̀rù rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 67:7
3
Saamu 67:4
Kí orílẹ̀-èdè kí ó yọ̀, kí ó sì kọrin fún ayọ̀, nítorí ìwọ fi òdodo darí àwọn ènìyàn, ìwọ sì jẹ ọba àwọn orílẹ̀-èdè ní ayé.
Ṣàwárí Saamu 67:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò