1
Saamu 69:30
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi yóò fi orin gbé orúkọ Ọlọ́run ga èmi yóò fi ọpẹ́ gbé orúkọ rẹ̀ ga.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 69:30
2
Saamu 69:13
Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti èmi ni ìwọ ni èmi ń gbàdúrà mi sí OLúWA, ní ìgbà ìtẹ́wọ́gbà Ọlọ́run, nínú ìfẹ́ títóbi rẹ, dá mi lóhùn pẹ̀lú ìgbàlà rẹ tí ó dájú.
Ṣàwárí Saamu 69:13
3
Saamu 69:16
Dá mí lóhùn, OLúWA, nínú ìṣeun ìfẹ́ rẹ; nínú ọ̀pọ̀ àánú rẹ yípadà sí mi.
Ṣàwárí Saamu 69:16
4
Saamu 69:33
OLúWA, gbọ́ ti aláìní, kì ó sì kọ àwọn ìgbèkùn sílẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 69:33
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò