1
Saamu 70:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ṣùgbọ́n kí àwọn tí ó ń wá ọ ó máa yọ̀ kí inú wọn kí ó sì máa dùn nípa rẹ, kí àwọn tí ó ń fẹ́ ìgbàlà rẹ máa wí pé, “Jẹ́ kí a gbé Ọlọ́run ga!”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 70:4
2
Saamu 70:5
Ṣùgbọ́n mo jẹ́ òtòṣì àti aláìní; wa kánkán sí ọ̀dọ̀ mi, Ọlọ́run. Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ àti olùdáǹdè mi; OLúWA, má ṣe dúró pẹ́.
Ṣàwárí Saamu 70:5
3
Saamu 70:1
Yára, Ọlọ́run, láti gbà mí là, OLúWA, wá kánkán láti ràn mí lọ́wọ́.
Ṣàwárí Saamu 70:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò