1
Saamu 71:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí ìwọ jẹ́ ìrètí mi, OLúWA Olódùmarè, ìwọ ni ìgbẹ́kẹ̀lé mi láti ìgbà èwe.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 71:5
2
Saamu 71:3
Jẹ́ àpáta ààbò mi, níbi tí èmi lè máa lọ, pa àṣẹ láti gbà mí, nítorí ìwọ ni àpáta àti odi agbára mi.
Ṣàwárí Saamu 71:3
3
Saamu 71:14
Ṣùgbọ́n ní tèmi, ìgbà gbogbo ní ìrètí mi; èmi ó yìn ọ́ síwájú àti síwájú sí i.
Ṣàwárí Saamu 71:14
4
Saamu 71:1
Nínú rẹ, OLúWA, ni mo ní ààbò; Má ṣe jẹ́ kí ojú kí ó tì mí.
Ṣàwárí Saamu 71:1
5
Saamu 71:8
Ìyìn rẹ̀ kún ẹnu mi, ó ń sọ ti ọlá rẹ ní ọjọ́ gbogbo.
Ṣàwárí Saamu 71:8
6
Saamu 71:15
Ẹnu mi yóò sọ nípa ti òdodo rẹ, ti ìgbàlà rẹ, ni gbogbo ọjọ́, lóòtítọ́, èmi kò mọ iye rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 71:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò