1
Saamu 72:18
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Olùbùkún ni OLúWA Ọlọ́run, Ọlọ́run Israẹli, ẹnìkan ṣoṣo tí ó ń ṣe ohun ìyanu.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 72:18
2
Saamu 72:19
Olùbùkún ni orúkọ rẹ̀ tí ó lógo títí láé; kí gbogbo ayé kún fún ògo rẹ̀. Àmín àti Àmín.
Ṣàwárí Saamu 72:19
3
Saamu 72:12
Nítorí yóò gba àwọn aláìní nígbà tí ó bá ń ké, tálákà àti ẹni tí kò ní olùrànlọ́wọ́.
Ṣàwárí Saamu 72:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò