1
Saamu 73:26
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ara mi àti ọkàn mi le è kùnà ṣùgbọ́n Ọlọ́run ni agbára ẹ̀mí mi àti ìpín mi títí láé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 73:26
2
Saamu 73:28
Ṣùgbọ́n ní ti èmi, ó dára láti súnmọ́ Ọlọ́run Èmi ti fi OLúWA Olódùmarè ṣe ààbò mi; Kí èmi ó lè máa sọ̀rọ̀ iṣẹ́ rẹ.
Ṣàwárí Saamu 73:28
3
Saamu 73:23-24
Síbẹ̀ mo wà pẹ̀lú rẹ nígbà gbogbo; ìwọ di ọwọ́ ọ̀tún mi mú. Ìwọ fi ìmọ̀ràn rẹ tọ́ mi ní ìkẹyìn ìwọ ó mú mi lọ sí inú ògo
Ṣàwárí Saamu 73:23-24
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò