Saamu 72:18

Saamu 72:18 YCB

Olùbùkún ni OLúWA Ọlọ́run, Ọlọ́run Israẹli, ẹnìkan ṣoṣo tí ó ń ṣe ohun ìyanu.