1
Saamu 92:12-13
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Olódodo yóò gbèrú bí i igi ọ̀pẹ, wọn yóò dàgbà bí i igi kedari Lebanoni, tí a gbìn sí ilé OLúWA, Wọn yóò rúwé nínú àgbàlá Ọlọ́run wa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 92:12-13
2
Saamu 92:14-15
Wọn yóò máa so èso ní ìgbà ogbó, wọn yóò dúró ní àkọ̀tun, wọn yóò sì tutù nini, láti fihàn pé, “Ẹni ìdúró ṣinṣin ni OLúWA; òun ni àpáta mi, kò sì ṣí aburú kankan nínú rẹ̀.”
Ṣàwárí Saamu 92:14-15