Saamu 92:12-13

Saamu 92:12-13 YCB

Olódodo yóò gbèrú bí i igi ọ̀pẹ, wọn yóò dàgbà bí i igi kedari Lebanoni; Tí a gbìn sí ilé OLúWA, Wọn yóò rúwé nínú àgbàlá Ọlọ́run wa.