O. Daf 92:12-13

O. Daf 92:12-13 YBCV

Olododo yio gbà bi igi ọpẹ: yio dàgba bi igi kedari Lebanoni. Awọn ẹniti a gbin ni ile Oluwa, yio gbà ni agbala Ọlọrun wa.