ORIN DAFIDI 92:12-13

ORIN DAFIDI 92:12-13 YCE

Àwọn olódodo yóo gbilẹ̀ bí igi ọ̀pẹ, wọn óo dàgbà bí igi kedari ti Lẹbanoni. Wọ́n dàbí igi tí a gbìn sí ilé OLUWA, tí ó sì ń dàgbà ninu àgbàlá Ọlọrun wa.