1
Saamu 94:19
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Nígbà tí àníyàn ńlá wà nínú mi, ìtùnú rẹ̀ mú ayọ̀ sí ọkàn mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 94:19
2
Saamu 94:18
Nígbà tí mo sọ pé, “Ẹsẹ̀ mi ń yọ̀”, OLúWA, ìfẹ́ rẹ̀ ni ó tì mí lẹ́yìn.
Ṣàwárí Saamu 94:18
3
Saamu 94:22
Ṣùgbọ́n, OLúWA ti di odi alágbára mi, àti Ọlọ́run mi ni àpáta nínú ẹni tí mo ti ń gba ààbò.
Ṣàwárí Saamu 94:22
4
Saamu 94:12
Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí ìwọ bá wí, OLúWA, ẹni tí ìwọ kọ́ nínú òfin rẹ
Ṣàwárí Saamu 94:12
5
Saamu 94:17
Bí kò ṣe pé OLúWA fún mi ní ìrànlọ́wọ́, èmi fẹ́rẹ̀ máa gbé ní ilẹ̀ tí ó dákẹ́.
Ṣàwárí Saamu 94:17
6
Saamu 94:14
Nítorí OLúWA kò ní kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀, Òun kò sì ní kọ ilẹ̀ ìní rẹ̀ sílẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 94:14